-
Róòmù 7:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ohun tí mò ń ṣe kò yé mi. Torí kì í ṣe ohun tí mo fẹ́ ni mò ń ṣe, àmọ́ ohun tí mo kórìíra ni mò ń ṣe.
-
-
Róòmù 7:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Nítorí kì í ṣe rere tí mo fẹ́ ni mò ń ṣe, búburú tí mi ò fẹ́ ni mò ń ṣe.
-