Gálátíà 5:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ẹ má ṣe jẹ́ kí a di agbéraga,+ kí a má ṣe máa bá ara wa díje,+ kí a má sì máa jowú ara wa.