Mátíù 13:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Àbí ọmọ káfíńtà kọ́ nìyí?+ Ṣebí Màríà lorúkọ ìyá rẹ̀, Jémíìsì, Jósẹ́fù, Símónì àti Júdásì sì ni àwọn arákùnrin rẹ̀?+ Ìṣe 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́, ó fọwọ́ sọ fún wọn pé kí wọ́n dákẹ́, ó sì sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ bí Jèhófà* ṣe mú un jáde kúrò nínú ẹ̀wọ̀n, ó sọ pé: “Ẹ sọ àwọn nǹkan yìí fún Jémíìsì+ àti àwọn ará.” Lẹ́yìn náà, ó jáde, ó sì rin ìrìn àjò lọ sí ibòmíì.
55 Àbí ọmọ káfíńtà kọ́ nìyí?+ Ṣebí Màríà lorúkọ ìyá rẹ̀, Jémíìsì, Jósẹ́fù, Símónì àti Júdásì sì ni àwọn arákùnrin rẹ̀?+
17 Àmọ́, ó fọwọ́ sọ fún wọn pé kí wọ́n dákẹ́, ó sì sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ bí Jèhófà* ṣe mú un jáde kúrò nínú ẹ̀wọ̀n, ó sọ pé: “Ẹ sọ àwọn nǹkan yìí fún Jémíìsì+ àti àwọn ará.” Lẹ́yìn náà, ó jáde, ó sì rin ìrìn àjò lọ sí ibòmíì.