Ìṣe 9:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nítorí náà, Bánábà+ ràn án lọ́wọ́, ó mú un lọ bá àwọn àpọ́sítélì, ó sì sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ bí ó ṣe rí Olúwa ní ojú ọ̀nà+ fún wọn àti pé Olúwa bá a sọ̀rọ̀. Ó tún sọ bó ṣe fìgboyà sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Jésù ní Damásíkù.+
27 Nítorí náà, Bánábà+ ràn án lọ́wọ́, ó mú un lọ bá àwọn àpọ́sítélì, ó sì sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ bí ó ṣe rí Olúwa ní ojú ọ̀nà+ fún wọn àti pé Olúwa bá a sọ̀rọ̀. Ó tún sọ bó ṣe fìgboyà sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Jésù ní Damásíkù.+