Ìṣe 16:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Pọ́ọ̀lù sọ ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ pé kí Tímótì tẹ̀ lé òun, ó mú un, ó sì dádọ̀dọ́ rẹ̀* nítorí àwọn Júù tó wà ní agbègbè yẹn,+ torí gbogbo wọn mọ̀ pé Gíríìkì ni bàbá rẹ̀.
3 Pọ́ọ̀lù sọ ìfẹ́ ọkàn rẹ̀ pé kí Tímótì tẹ̀ lé òun, ó mú un, ó sì dádọ̀dọ́ rẹ̀* nítorí àwọn Júù tó wà ní agbègbè yẹn,+ torí gbogbo wọn mọ̀ pé Gíríìkì ni bàbá rẹ̀.