2 Kọ́ríńtì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà* ni Ẹ̀mí náà,+ ibi tí ẹ̀mí Jèhófà* bá sì wà, òmìnira á wà níbẹ̀.+ Gálátíà 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kristi ti dá wa sílẹ̀ ká lè ní irú òmìnira yìí. Nítorí náà, ẹ dúró gbọn-in,+ ẹ má sì tọrùn bọ àjàgà ẹrú mọ́.+
5 Kristi ti dá wa sílẹ̀ ká lè ní irú òmìnira yìí. Nítorí náà, ẹ dúró gbọn-in,+ ẹ má sì tọrùn bọ àjàgà ẹrú mọ́.+