2 Kọ́ríńtì 5:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó sì kú fún gbogbo wọn kí àwọn tó wà láàyè má ṣe tún wà láàyè fún ara wọn mọ́,+ bí kò ṣe fún ẹni tó kú fún wọn, tí a sì gbé dìde.
15 Ó sì kú fún gbogbo wọn kí àwọn tó wà láàyè má ṣe tún wà láàyè fún ara wọn mọ́,+ bí kò ṣe fún ẹni tó kú fún wọn, tí a sì gbé dìde.