Ìṣe 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nígbà tí Pọ́ọ̀lù rí i pé apá kan wọn jẹ́ Sadusí, àwọn tó kù sì jẹ́ Farisí, ó ké jáde ní Sàhẹ́ndìrìn pé: “Ẹ̀yin èèyàn, ẹ̀yin ará, Farisí ni mí,+ mo sì jẹ́ ọmọ àwọn Farisí. Torí ìrètí àjíǹde àwọn òkú ni wọ́n ṣe ń dá mi lẹ́jọ́.”
6 Nígbà tí Pọ́ọ̀lù rí i pé apá kan wọn jẹ́ Sadusí, àwọn tó kù sì jẹ́ Farisí, ó ké jáde ní Sàhẹ́ndìrìn pé: “Ẹ̀yin èèyàn, ẹ̀yin ará, Farisí ni mí,+ mo sì jẹ́ ọmọ àwọn Farisí. Torí ìrètí àjíǹde àwọn òkú ni wọ́n ṣe ń dá mi lẹ́jọ́.”