Róòmù 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́, ẹ gbé Olúwa Jésù Kristi wọ̀,+ ẹ má sì máa gbèrò àwọn ìfẹ́ ti ara.+ Éfésù 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 kí ẹ sì gbé ìwà tuntun wọ̀,+ èyí tí a dá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run nínú òdodo tòótọ́ àti ìdúróṣinṣin.
24 kí ẹ sì gbé ìwà tuntun wọ̀,+ èyí tí a dá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run nínú òdodo tòótọ́ àti ìdúróṣinṣin.