14 Torí náà, Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara,+ ó gbé láàárín wa, a sì rí ògo rẹ̀, irú ògo tó jẹ́ ti ọmọ bíbí kan ṣoṣo+ ti bàbá kan; ó sì kún fún oore Ọlọ́run* àti òtítọ́.
14 Nítorí náà, torí pé “àwọn ọmọ kéékèèké” ní ẹ̀jẹ̀ àti ẹran ara, òun náà wá ní ẹ̀jẹ̀ àti ẹran ara,+ kó lè tipasẹ̀ ikú rẹ̀ pa ẹni tó lè fa ikú run,+ ìyẹn Èṣù,+