Mátíù 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Ẹ má rò pé mo wá láti pa Òfin tàbí àwọn Wòlíì run. Mi ò wá láti pa á run, àmọ́ láti mú un ṣẹ.+