Róòmù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 ìrètí kì í sì í yọrí sí ìjákulẹ̀;+ nítorí pé a ti tú ìfẹ́ Ọlọ́run jáde sínú ọkàn wa nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́, èyí tí a fún wa.+
5 ìrètí kì í sì í yọrí sí ìjákulẹ̀;+ nítorí pé a ti tú ìfẹ́ Ọlọ́run jáde sínú ọkàn wa nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́, èyí tí a fún wa.+