Róòmù 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí a mọ̀ pé a ti kan ìwà wa àtijọ́ mọ́gi* pẹ̀lú rẹ̀,+ kí ara ẹ̀ṣẹ̀ wa lè di aláìlágbára,+ kí a má ṣe jẹ́ ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ mọ́.+ Kólósè 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ má ṣe máa parọ́ fún ara yín.+ Ẹ bọ́ ìwà* àtijọ́ sílẹ̀+ pẹ̀lú àwọn àṣà rẹ̀,
6 Torí a mọ̀ pé a ti kan ìwà wa àtijọ́ mọ́gi* pẹ̀lú rẹ̀,+ kí ara ẹ̀ṣẹ̀ wa lè di aláìlágbára,+ kí a má ṣe jẹ́ ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ mọ́.+