-
Róòmù 13:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Òru ti lọ jìnnà; ilẹ̀ ti fẹ́rẹ̀ẹ́ mọ́. Torí náà, ẹ jẹ́ ká ju àwọn iṣẹ́ tó jẹ́ ti òkùnkùn nù,+ ká sì gbé àwọn ohun ìjà ìmọ́lẹ̀ wọ̀.+ 13 Ẹ jẹ́ ká máa rìn lọ́nà tó bójú mu+ bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán, kì í ṣe nínú àwọn àríyá aláriwo àti ìmutípara, kì í ṣe nínú ìṣekúṣe àti ìwà àìnítìjú,*+ kì í ṣe nínú wàhálà àti owú.+
-