Éfésù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Síwájú sí i, Ọlọ́run sọ yín di ààyè, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ ti kú nínú àṣemáṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ yín,+ Kólósè 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Yàtọ̀ síyẹn, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ ti kú nínú àwọn àṣemáṣe yín àti nínú ipò àìdádọ̀dọ́* ẹran ara yín, Ọlọ́run mú kí ẹ wà láàyè pẹ̀lú rẹ̀.+ Ó dárí gbogbo àṣemáṣe wa jì wá tinútinú,+
13 Yàtọ̀ síyẹn, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ ti kú nínú àwọn àṣemáṣe yín àti nínú ipò àìdádọ̀dọ́* ẹran ara yín, Ọlọ́run mú kí ẹ wà láàyè pẹ̀lú rẹ̀.+ Ó dárí gbogbo àṣemáṣe wa jì wá tinútinú,+