Sáàmù 33:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ fi háàpù dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà;Ẹ fi orin yìn ín* pẹ̀lú ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín mẹ́wàá. 3 Ẹ kọ orin tuntun sí i;+Ẹ fi ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín dárà, bí ẹ ti ń kígbe ayọ̀.
2 Ẹ fi háàpù dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà;Ẹ fi orin yìn ín* pẹ̀lú ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín mẹ́wàá. 3 Ẹ kọ orin tuntun sí i;+Ẹ fi ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín dárà, bí ẹ ti ń kígbe ayọ̀.