1 Kọ́ríńtì 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́ mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé orí gbogbo ọkùnrin ni Kristi; + bákan náà, orí obìnrin ni ọkùnrin;+ bákan náà, orí Kristi ni Ọlọ́run.+
3 Àmọ́ mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé orí gbogbo ọkùnrin ni Kristi; + bákan náà, orí obìnrin ni ọkùnrin;+ bákan náà, orí Kristi ni Ọlọ́run.+