Kólósè 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ẹ̀yin ẹrú, ẹ máa gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín* lẹ́nu nínú ohun gbogbo,+ kì í ṣe nígbà tí wọ́n bá ń wò yín nìkan, torí kí ẹ lè tẹ́ èèyàn lọ́rùn,* àmọ́ ẹ máa fòótọ́ ọkàn ṣe é pẹ̀lú ìbẹ̀rù Jèhófà.*
22 Ẹ̀yin ẹrú, ẹ máa gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín* lẹ́nu nínú ohun gbogbo,+ kì í ṣe nígbà tí wọ́n bá ń wò yín nìkan, torí kí ẹ lè tẹ́ èèyàn lọ́rùn,* àmọ́ ẹ máa fòótọ́ ọkàn ṣe é pẹ̀lú ìbẹ̀rù Jèhófà.*