1 Kọ́ríńtì 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ẹnikẹ́ni tí a pè nínú Olúwa nígbà tó jẹ́ ẹrú ti di òmìnira nínú Olúwa; + bákan náà, ẹnikẹ́ni tí a pè nígbà tó wà ní òmìnira jẹ́ ẹrú Kristi.
22 Nítorí ẹnikẹ́ni tí a pè nínú Olúwa nígbà tó jẹ́ ẹrú ti di òmìnira nínú Olúwa; + bákan náà, ẹnikẹ́ni tí a pè nígbà tó wà ní òmìnira jẹ́ ẹrú Kristi.