2 Tímótì 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo ti ja ìjà rere náà,+ mo ti sá eré ìje náà dé ìparí,+ mo ti pa ìgbàgbọ́ mọ́.