1 Tímótì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 torí tí mi ò bá tètè dé, kí o lè mọ bó ṣe yẹ kí o máa hùwà nínú ilé Ọlọ́run,+ tó jẹ́ ìjọ Ọlọ́run alààyè, òpó àti ìtìlẹyìn òtítọ́. Hébérù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 àmọ́ Kristi jẹ́ olóòótọ́ ọmọ+ lórí ilé Ọlọ́run. Àwa ni ilé Rẹ̀,+ tí a bá rí i dájú pé a ò jẹ́ kí ohunkóhun dí wa lọ́wọ́ láti máa sọ̀rọ̀ ní fàlàlà, tí a sì di ìrètí tí a fi ń yangàn mú ṣinṣin títí dé òpin.
15 torí tí mi ò bá tètè dé, kí o lè mọ bó ṣe yẹ kí o máa hùwà nínú ilé Ọlọ́run,+ tó jẹ́ ìjọ Ọlọ́run alààyè, òpó àti ìtìlẹyìn òtítọ́.
6 àmọ́ Kristi jẹ́ olóòótọ́ ọmọ+ lórí ilé Ọlọ́run. Àwa ni ilé Rẹ̀,+ tí a bá rí i dájú pé a ò jẹ́ kí ohunkóhun dí wa lọ́wọ́ láti máa sọ̀rọ̀ ní fàlàlà, tí a sì di ìrètí tí a fi ń yangàn mú ṣinṣin títí dé òpin.