-
Róòmù 16:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ní báyìí, Ẹni tó lè fìdí yín múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìhìn rere tí mò ń kéde àti ìwàásù Jésù Kristi, gẹ́gẹ́ bí ìfihàn àṣírí mímọ́+ tí a ti pa mọ́ ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́ látọjọ́ pípẹ́, 26 àmọ́ tí a ti fi hàn kedere* ní báyìí, ti a sì jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ̀ ọ́n láàárín gbogbo orílẹ̀-èdè nípasẹ̀ àwọn Ìwé Mímọ́ alásọtẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Ọlọ́run ayérayé pa pé ká fi ìgbàgbọ́ gbé ìgbọràn ga;
-