-
2 Kọ́ríńtì 4:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nítorí náà, a kò juwọ́ sílẹ̀, kódà bí ẹni tí a jẹ́ ní òde bá tilẹ̀ ń joro, ó dájú pé ẹni tí a jẹ́ ní inú ń di ọ̀tun láti ọjọ́ dé ọjọ́.
-