Jòhánù 14:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jésù dá a lóhùn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá nífẹ̀ẹ́ mi, ó máa pa ọ̀rọ̀ mi mọ́,+ Baba mi sì máa nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, a máa wá sọ́dọ̀ rẹ̀, a sì máa fi ọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣe ibùgbé* wa.+
23 Jésù dá a lóhùn pé: “Tí ẹnikẹ́ni bá nífẹ̀ẹ́ mi, ó máa pa ọ̀rọ̀ mi mọ́,+ Baba mi sì máa nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, a máa wá sọ́dọ̀ rẹ̀, a sì máa fi ọ̀dọ̀ rẹ̀ ṣe ibùgbé* wa.+