Kólósè 2:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí náà, bí ẹ ṣe tẹ́wọ́ gba Kristi Jésù Olúwa, ẹ máa rìn ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, 7 kí ẹ ta gbòǹgbò, kí ẹ sì máa dàgbà nínú rẹ̀,+ kí ẹ fẹsẹ̀ múlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́,+ bí a ṣe kọ́ yín, kí ẹ sì máa kún fún ọpẹ́.+
6 Nítorí náà, bí ẹ ṣe tẹ́wọ́ gba Kristi Jésù Olúwa, ẹ máa rìn ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, 7 kí ẹ ta gbòǹgbò, kí ẹ sì máa dàgbà nínú rẹ̀,+ kí ẹ fẹsẹ̀ múlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́,+ bí a ṣe kọ́ yín, kí ẹ sì máa kún fún ọpẹ́.+