Róòmù 8:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ta ló máa yà wá kúrò nínú ìfẹ́ Kristi? + Ṣé ìpọ́njú ni àbí wàhálà àbí inúnibíni àbí ebi àbí ìhòòhò àbí ewu àbí idà?+
35 Ta ló máa yà wá kúrò nínú ìfẹ́ Kristi? + Ṣé ìpọ́njú ni àbí wàhálà àbí inúnibíni àbí ebi àbí ìhòòhò àbí ewu àbí idà?+