Róòmù 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nítorí pé tí a bá wà láàyè, a wà láàyè fún Jèhófà,*+ tí a bá sì kú, a kú fún Jèhófà.* Torí náà, tí a bá wà láàyè tàbí tí a bá kú, a jẹ́ ti Jèhófà.*+ 1 Pétérù 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni bá jìyà torí pé ó jẹ́ Kristẹni, kó má ṣe tijú,+ àmọ́ kó túbọ̀ máa yin Ọlọ́run lógo bó ṣe ń jẹ́ orúkọ yìí.
8 Nítorí pé tí a bá wà láàyè, a wà láàyè fún Jèhófà,*+ tí a bá sì kú, a kú fún Jèhófà.* Torí náà, tí a bá wà láàyè tàbí tí a bá kú, a jẹ́ ti Jèhófà.*+
16 Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni bá jìyà torí pé ó jẹ́ Kristẹni, kó má ṣe tijú,+ àmọ́ kó túbọ̀ máa yin Ọlọ́run lógo bó ṣe ń jẹ́ orúkọ yìí.