Jòhánù 5:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí Baba kì í ṣèdájọ́ ẹnikẹ́ni, àmọ́ ó ti fi gbogbo ìdájọ́ lé Ọmọ lọ́wọ́,+ 23 kí gbogbo ẹ̀dá lè máa bọlá fún Ọmọ bí wọ́n ṣe ń bọlá fún Baba. Ẹnikẹ́ni tí kò bá bọlá fún Ọmọ, kò bọlá fún Baba tó rán an.+
22 Torí Baba kì í ṣèdájọ́ ẹnikẹ́ni, àmọ́ ó ti fi gbogbo ìdájọ́ lé Ọmọ lọ́wọ́,+ 23 kí gbogbo ẹ̀dá lè máa bọlá fún Ọmọ bí wọ́n ṣe ń bọlá fún Baba. Ẹnikẹ́ni tí kò bá bọlá fún Ọmọ, kò bọlá fún Baba tó rán an.+