Fílípì 4:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àmọ́, mo ní ohun gbogbo tí mo nílò, kódà mo ní jù bẹ́ẹ̀ lọ. Mo ti ní ànító, ní báyìí tí àwọn ohun tí ẹ fi rán Ẹpafíródítù+ ti dé ọwọ́ mi, wọ́n dà bí òórùn dídùn,+ ẹbọ tó ṣe ìtẹ́wọ́gbà, tó sì wu Ọlọ́run gidigidi.
18 Àmọ́, mo ní ohun gbogbo tí mo nílò, kódà mo ní jù bẹ́ẹ̀ lọ. Mo ti ní ànító, ní báyìí tí àwọn ohun tí ẹ fi rán Ẹpafíródítù+ ti dé ọwọ́ mi, wọ́n dà bí òórùn dídùn,+ ẹbọ tó ṣe ìtẹ́wọ́gbà, tó sì wu Ọlọ́run gidigidi.