-
Róòmù 4:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ṣùgbọ́n lójú ẹni tí kò ṣiṣẹ́, àmọ́ tó ní ìgbàgbọ́ nínú Ẹni tó ń pe àwọn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ní olódodo, ìgbàgbọ́ rẹ̀ ni a kà sí òdodo.+
-