Lúùkù 9:62 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 62 Jésù sọ fún un pé: “Ẹnikẹ́ni tó bá fi ọwọ́ rẹ̀ lé ohun ìtúlẹ̀, tó wá wo àwọn ohun tó wà lẹ́yìn,+ kò yẹ fún Ìjọba Ọlọ́run.”+
62 Jésù sọ fún un pé: “Ẹnikẹ́ni tó bá fi ọwọ́ rẹ̀ lé ohun ìtúlẹ̀, tó wá wo àwọn ohun tó wà lẹ́yìn,+ kò yẹ fún Ìjọba Ọlọ́run.”+