ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Tímótì 4:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Láti ìsinsìnyí lọ, a ti fi adé òdodo  + pa mọ́ dè mí, èyí tí Olúwa, onídàájọ́ òdodo,+ máa fi san mí lẹ́san ní ọjọ́ yẹn,+ síbẹ̀ kì í ṣe fún èmi nìkan, àmọ́ fún gbogbo àwọn tó nífẹ̀ẹ́ ìfarahàn rẹ̀.

  • Hébérù 12:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Nígbà náà, torí pé a ní àwọsánmà àwọn ẹlẹ́rìí tó pọ̀ gan-an yí wa ká, ẹ jẹ́ kí àwa náà ju gbogbo ẹrù tó wúwo nù àti ẹ̀ṣẹ̀ tó máa ń wé mọ́ wa tìrọ̀rùn-tìrọ̀rùn,+ ká sì máa fi ìfaradà sá eré ìje tó wà níwájú wa,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́