Fílípì 1:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Kìkì pé kí ẹ máa hùwà* lọ́nà tó yẹ ìhìn rere nípa Kristi,+ kó lè jẹ́ pé, bóyá mo wá wò yín tàbí mi ò wá, kí n lè máa gbọ́ nípa yín pé ẹ dúró gbọn-in nínú ẹ̀mí kan, pẹ̀lú ọkàn kan,*+ ẹ jọ ń sapá nítorí ìgbàgbọ́ nínú ìhìn rere,
27 Kìkì pé kí ẹ máa hùwà* lọ́nà tó yẹ ìhìn rere nípa Kristi,+ kó lè jẹ́ pé, bóyá mo wá wò yín tàbí mi ò wá, kí n lè máa gbọ́ nípa yín pé ẹ dúró gbọn-in nínú ẹ̀mí kan, pẹ̀lú ọkàn kan,*+ ẹ jọ ń sapá nítorí ìgbàgbọ́ nínú ìhìn rere,