Jòhánù 16:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Mo ti sọ àwọn nǹkan yìí fún yín kí ẹ lè ní àlàáfíà nípasẹ̀ mi.+ Ẹ máa ní ìpọ́njú nínú ayé, àmọ́ ẹ mọ́kàn le! Mo ti ṣẹ́gun ayé.”+ Róòmù 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tóò, ní báyìí tí a ti pè wá ní olódodo nítorí ìgbàgbọ́,+ ẹ jẹ́ kí a máa gbádùn àlàáfíà* pẹ̀lú Ọlọ́run nípasẹ̀ Olúwa wa Jésù Kristi,+
33 Mo ti sọ àwọn nǹkan yìí fún yín kí ẹ lè ní àlàáfíà nípasẹ̀ mi.+ Ẹ máa ní ìpọ́njú nínú ayé, àmọ́ ẹ mọ́kàn le! Mo ti ṣẹ́gun ayé.”+
5 Tóò, ní báyìí tí a ti pè wá ní olódodo nítorí ìgbàgbọ́,+ ẹ jẹ́ kí a máa gbádùn àlàáfíà* pẹ̀lú Ọlọ́run nípasẹ̀ Olúwa wa Jésù Kristi,+