1 Kọ́ríńtì 14:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Kí wá ni ṣíṣe, ẹ̀yin ará? Nígbà tí ẹ bá kóra jọ, ẹnì kan ní sáàmù, ẹlòmíì ní ẹ̀kọ́, ẹlòmíì ní ìfihàn, ẹlòmíì ní èdè* àjèjì, ẹlòmíì sì ní ìtúmọ̀.+ Kí ohun gbogbo máa ṣẹlẹ̀ láti gbéni ró.
26 Kí wá ni ṣíṣe, ẹ̀yin ará? Nígbà tí ẹ bá kóra jọ, ẹnì kan ní sáàmù, ẹlòmíì ní ẹ̀kọ́, ẹlòmíì ní ìfihàn, ẹlòmíì ní èdè* àjèjì, ẹlòmíì sì ní ìtúmọ̀.+ Kí ohun gbogbo máa ṣẹlẹ̀ láti gbéni ró.