1 Pétérù 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ṣùgbọ́n ẹ gbà nínú ọkàn yín pé Kristi jẹ́ mímọ́, òun ni Olúwa, kí ẹ ṣe tán nígbà gbogbo láti gbèjà ara yín níwájú gbogbo ẹni tó bá béèrè ìdí tí ẹ fi ní ìrètí yìí, àmọ́ kí ẹ máa fi ìwà tútù+ àti ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀ ṣe bẹ́ẹ̀.+
15 Ṣùgbọ́n ẹ gbà nínú ọkàn yín pé Kristi jẹ́ mímọ́, òun ni Olúwa, kí ẹ ṣe tán nígbà gbogbo láti gbèjà ara yín níwájú gbogbo ẹni tó bá béèrè ìdí tí ẹ fi ní ìrètí yìí, àmọ́ kí ẹ máa fi ìwà tútù+ àti ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀ ṣe bẹ́ẹ̀.+