Fílémónì 1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Pọ́ọ̀lù, tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n+ nítorí Kristi Jésù, àti Tímótì+ arákùnrin wa, sí Fílémónì, ẹni ọ̀wọ́n tí a jọ ń ṣiṣẹ́, 2 àti sí Áfíà arábìnrin wa àti Ákípọ́sì+ tí a jọ jẹ́ ọmọ ogun àti sí ìjọ tó wà ní ilé rẹ:+
1 Pọ́ọ̀lù, tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n+ nítorí Kristi Jésù, àti Tímótì+ arákùnrin wa, sí Fílémónì, ẹni ọ̀wọ́n tí a jọ ń ṣiṣẹ́, 2 àti sí Áfíà arábìnrin wa àti Ákípọ́sì+ tí a jọ jẹ́ ọmọ ogun àti sí ìjọ tó wà ní ilé rẹ:+