1 Kọ́ríńtì 1:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ṣùgbọ́n òun ló mú kí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù, ẹni tó fi ọgbọ́n Ọlọ́run àti òdodo rẹ̀+ hàn wá, ó sọ wá di mímọ́,+ ó sì tú wa sílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà,+ 1 Kọ́ríńtì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí “ta ló ti wá mọ èrò inú Jèhófà,* kí ó lè kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́?”+ Àmọ́ àwa ní èrò inú Kristi.+
30 Ṣùgbọ́n òun ló mú kí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù, ẹni tó fi ọgbọ́n Ọlọ́run àti òdodo rẹ̀+ hàn wá, ó sọ wá di mímọ́,+ ó sì tú wa sílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà,+