29 Àmọ́ ẹni tó jẹ́ Júù ní inú ni Júù,+ ìdádọ̀dọ́* rẹ̀ sì jẹ́ ti ọkàn+ nípa ẹ̀mí, kì í ṣe nípa àkọsílẹ̀ òfin.+ Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ìyìn ẹni yẹn ti wá, kì í ṣe láti ọ̀dọ̀ èèyàn.+
3 Nítorí àwa ni a dádọ̀dọ́* lóòótọ́,+ àwa tí à ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ nípasẹ̀ ẹ̀mí Ọlọ́run, tí à ń fi Kristi Jésù yangàn,+ tí a ò sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹran ara,