Róòmù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí náà, a sin wá pọ̀ pẹ̀lú rẹ̀ nípasẹ̀ ìbatisí wa sínú ikú rẹ̀,+ kí ó lè jẹ́ pé bí a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú nípasẹ̀ ògo Baba, kí àwa náà lè máa gbé ìgbé ayé ọ̀tun.+
4 Nítorí náà, a sin wá pọ̀ pẹ̀lú rẹ̀ nípasẹ̀ ìbatisí wa sínú ikú rẹ̀,+ kí ó lè jẹ́ pé bí a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú nípasẹ̀ ògo Baba, kí àwa náà lè máa gbé ìgbé ayé ọ̀tun.+