Róòmù 14:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹni tó ń pa ọjọ́ kan mọ́ ń pa á mọ́ fún Jèhófà.* Bákan náà, ẹni tó ń jẹun, ń jẹun fún Jèhófà,* nítorí ó ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run;+ ẹni tí kò sì jẹun kò jẹun fún Jèhófà,* síbẹ̀, ó ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run.+
6 Ẹni tó ń pa ọjọ́ kan mọ́ ń pa á mọ́ fún Jèhófà.* Bákan náà, ẹni tó ń jẹun, ń jẹun fún Jèhófà,* nítorí ó ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run;+ ẹni tí kò sì jẹun kò jẹun fún Jèhófà,* síbẹ̀, ó ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run.+