Gálátíà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bákan náà, ní tiwa, nígbà tí a wà lọ́mọdé, àwọn èrò àti ìṣe ayé* ń mú wa lẹ́rú.+ Kólósè 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ máa ṣọ́ra kí ẹnikẹ́ni má fi ọgbọ́n orí àti ìtànjẹ lásán+ mú yín lẹ́rú* látinú òfin àtọwọ́dọ́wọ́ èèyàn, nínú àwọn ohun àkọ́bẹ̀rẹ̀ ayé, tí kì í ṣe nínú Kristi;
8 Ẹ máa ṣọ́ra kí ẹnikẹ́ni má fi ọgbọ́n orí àti ìtànjẹ lásán+ mú yín lẹ́rú* látinú òfin àtọwọ́dọ́wọ́ èèyàn, nínú àwọn ohun àkọ́bẹ̀rẹ̀ ayé, tí kì í ṣe nínú Kristi;