1 Tẹsalóníkà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí ẹ̀yin fúnra yín mọ̀ dáadáa pé ọjọ́ Jèhófà*+ ń bọ̀ bí olè ní òru.+ 2 Pétérù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 bí ẹ ti ń dúró de ìgbà tí ọjọ́ Jèhófà*+ máa wà níhìn-ín, tí ẹ sì ń fi í sọ́kàn dáadáa,* nípasẹ̀ èyí tí àwọn ọ̀run máa pa run + nínú iná, tí àwọn ohun ìpìlẹ̀ máa yọ́ nítorí ooru tó gbóná janjan!
12 bí ẹ ti ń dúró de ìgbà tí ọjọ́ Jèhófà*+ máa wà níhìn-ín, tí ẹ sì ń fi í sọ́kàn dáadáa,* nípasẹ̀ èyí tí àwọn ọ̀run máa pa run + nínú iná, tí àwọn ohun ìpìlẹ̀ máa yọ́ nítorí ooru tó gbóná janjan!