Ìṣe 17:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wọ́n rin ìrìn àjò gba Áńfípólì àti Apolóníà kọjá, wọ́n sì wá sí Tẹsalóníkà,+ níbi tí sínágọ́gù àwọn Júù wà. 2 Torí náà, bí àṣà Pọ́ọ̀lù,+ ó wọlé lọ bá wọn, ó sì bá wọn fèròwérò látinú Ìwé Mímọ́ fún sábáàtì mẹ́ta,+
17 Wọ́n rin ìrìn àjò gba Áńfípólì àti Apolóníà kọjá, wọ́n sì wá sí Tẹsalóníkà,+ níbi tí sínágọ́gù àwọn Júù wà. 2 Torí náà, bí àṣà Pọ́ọ̀lù,+ ó wọlé lọ bá wọn, ó sì bá wọn fèròwérò látinú Ìwé Mímọ́ fún sábáàtì mẹ́ta,+