Éfésù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí náà, èmi, ẹlẹ́wọ̀n+ nínú Olúwa, pàrọwà fún yín láti máa rìn lọ́nà tó yẹ+ pípè tí a pè yín, Kólósè 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 kí ẹ lè máa rìn lọ́nà tó yẹ Jèhófà* láti ṣe ìfẹ́ rẹ̀ ní kíkún, bí ẹ ṣe ń so èso nínú gbogbo iṣẹ́ rere, tí ìmọ̀ tó péye tí ẹ ní nípa Ọlọ́run sì ń pọ̀ sí i;+ 1 Pétérù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+
10 kí ẹ lè máa rìn lọ́nà tó yẹ Jèhófà* láti ṣe ìfẹ́ rẹ̀ ní kíkún, bí ẹ ṣe ń so èso nínú gbogbo iṣẹ́ rere, tí ìmọ̀ tó péye tí ẹ ní nípa Ọlọ́run sì ń pọ̀ sí i;+