Ìṣe 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́ inú bí àwọn Júù,+ wọ́n kó àwọn ọkùnrin burúkú kan jọ tí wọ́n jẹ́ aláìríkan-ṣèkan ní ibi ọjà, wọ́n di àwùjọ onírúgúdù, wọ́n sì dá ìdàrúdàpọ̀ sílẹ̀ nínú ìlú náà. Wọ́n ya wọ ilé Jásónì, wọ́n ń wá ọ̀nà láti mú Pọ́ọ̀lù àti Sílà wá fún àwùjọ náà.
5 Àmọ́ inú bí àwọn Júù,+ wọ́n kó àwọn ọkùnrin burúkú kan jọ tí wọ́n jẹ́ aláìríkan-ṣèkan ní ibi ọjà, wọ́n di àwùjọ onírúgúdù, wọ́n sì dá ìdàrúdàpọ̀ sílẹ̀ nínú ìlú náà. Wọ́n ya wọ ilé Jásónì, wọ́n ń wá ọ̀nà láti mú Pọ́ọ̀lù àti Sílà wá fún àwùjọ náà.