Ìṣe 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí àwọn tó wà pẹ̀lú Pọ́ọ̀lù mú un dé Áténì, wọ́n pa dà lẹ́yìn tí Pọ́ọ̀lù sọ fún wọn pé kí Sílà àti Tímótì+ tètè wá bá òun ní kíá.
15 Nígbà tí àwọn tó wà pẹ̀lú Pọ́ọ̀lù mú un dé Áténì, wọ́n pa dà lẹ́yìn tí Pọ́ọ̀lù sọ fún wọn pé kí Sílà àti Tímótì+ tètè wá bá òun ní kíá.