2 Tẹsalóníkà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí èyí, à ń fi yín yangàn+ láàárín ìjọ Ọlọ́run nítorí ìfaradà àti ìgbàgbọ́ yín nínú gbogbo inúnibíni àti àwọn ìṣòro* tí ẹ̀ ń dojú kọ.*+
4 Nítorí èyí, à ń fi yín yangàn+ láàárín ìjọ Ọlọ́run nítorí ìfaradà àti ìgbàgbọ́ yín nínú gbogbo inúnibíni àti àwọn ìṣòro* tí ẹ̀ ń dojú kọ.*+