2 Tẹsalóníkà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ̀yin ará, ó di dandan fún wa láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nígbà gbogbo nítorí yín. Ó yẹ bẹ́ẹ̀, torí pé ìgbàgbọ́ yín ń lágbára sí i, ìfẹ́ tí ẹ ní sí ara yín lẹ́nì kọ̀ọ̀kan àti lápapọ̀ sì ń pọ̀ sí i.+
3 Ẹ̀yin ará, ó di dandan fún wa láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nígbà gbogbo nítorí yín. Ó yẹ bẹ́ẹ̀, torí pé ìgbàgbọ́ yín ń lágbára sí i, ìfẹ́ tí ẹ ní sí ara yín lẹ́nì kọ̀ọ̀kan àti lápapọ̀ sì ń pọ̀ sí i.+