19 Mò ń lo ọ̀rọ̀ tí èèyàn lè tètè lóye nítorí àìlera ara yín; torí bí ẹ ṣe fi àwọn ẹ̀yà ara yín ṣe ẹrú ìwà àìmọ́ àti ìwà tí kò bófin mu tó ń yọrí sí ìwà tí kò bófin mu, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ fi àwọn ẹ̀yà ara yín ṣe ẹrú ní báyìí fún òdodo tó ń yọrí sí ìjẹ́mímọ́.+